Olo Omidan Bata: Ìlù Bàtá ló yàn mi, èmi kọ́ ni mo yàn an

Ó ma ń jẹ́ ohun ìyàlẹ́nu láti rí obìnrin tó ń lu àwọn ìlù ìbílẹ̀ Yorùbá. Omidan yìí, Ibukun Ayoola jẹ́wọ́ ọmọ̀ Yorùbá tó jẹ́ àti olólùfẹ́ àṣà àti ìṣe Yorùbá.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: