Violence against Women: Àlùfáà Joel Olugbenga: Bíbélì kò ní kéèyàn dúró títí ọkọ rẹ̀ yóò fi lù ú pa

Violence against Women: Àlùfáà Joel Olugbenga: Bíbélì kò ní kéèyàn dúró títí ọkọ rẹ̀ yóò fi lù ú pa

Ìwà ipá nínú ilé ti rìn jìnà gẹ́gẹ́ bíi kòkòrò ajẹnirun tó ti ń tú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdílé ká. Ṣùgbọ́n àwọn onímọ̀ ẹ̀sìn sọ pé ohun àá ṣeé ṣì kù.

Oriṣiriṣi nnkan lo n ṣẹlẹ lasiko yii, ni eyi to ti n mu ki a nlu ara ẹni n waye ninu idile.

Ni igba miiran, awọn iṣẹlẹ yii maa n ṣokunfa iku ọkọ tabi aya ni asiko yii.

BBC Yoruba gbalejo Alagba Joel Olugbenga lati ile ijọsin Redeemed Christian Church of God lati sọrọ lori ohun ti Bibeli sọ lori kikọ ara ẹni silẹ ninu idile.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí:

Oluṣọagutan Joel Olugbenga, to jẹ APICP FCT 6 nilu Abuja gba awọn kristiẹni nimọran lori ọrọ ipa ninu idile.

O sọju abẹ niko pe igbeyawo ko gbọdọ la ẹmi lọ mọ, ẹ le yẹra funra yin ki alaafia fi jọba.