Adejọkẹ Lasisi: Àṣà wa ti ń lọ, wọ́n ń gbàgbé nípa rẹ̀

Àwọ́n Yorùbá ní ká kọ́ bí wọ́n ṣe ń rákò ká tó bẹ̀rẹ̀ sí ń rìn, kẹ̀rẹ̀ kẹ̀rẹ̀ Adéjọkẹ́ Lasisi ti ibi plẹbẹ m'ọ́ọ̀lẹ̀ jẹ́ títí tí iṣẹ̀ fífi aṣọ òkè ṣe àwọn àrà àti ọ̀ṣọ́ ìgbàlódé ṣe wá di irú di igba mọ́ ọ lọ́wọ́. Ǹjẹ́ ẹ lè mọ̀ pé aṣọ òkè ni wọ́n fi ṣe ẹ̀ṣọ́ orí, Báàgi àpamábíyá, Bàta, ẹ̀gbà ọ́wọ́?

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: