Ọkọ̀ agbépo tí kò ní búrékì pa ènìyàn mẹ́rin n‘Ibadan
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ìjàmbá Ibadan: Abiyamọ tó pọn ọmọ sẹ́yìn kú tọmọ-tọmọ

Ọjọ buruku esu gbomi mu ni lagbegbe Ring Road ni ilu Ibadan nigba ti ọkọ agbepo kan pa eniyan mẹrin.

Awọn ti ọrọ naa soju rẹ ni, ọkọ agbepo naa ko ni bureki tabi o kọ̀ lati sisẹ ni ọkọ naa ba ya wọ sọọbu kan.

Ọkọ naa si tun lọ pa arabinrin to gbe ọmọ sẹyin lori ọkada pẹlu awọn eeyan miran to faragba ninu isẹlẹ na.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: