Ezekwesili: Mo fẹ́ sọ Nàíjíríà di ilẹ̀ tí àǹfàní ọgbọọgba wà
Ezekwesili: Mo fẹ́ sọ Nàíjíríà di ilẹ̀ tí àǹfàní ọgbọọgba wà
Oby Ezekwesili, tii se minisita tẹlẹ ati oludari ikọ to n kigbe fun awari awọn ọmọdebinrin ti Boko Haram ji gbe ni, to ba jẹ awọn ọmọ olowo ni Boko Haram ji gbe nigba to ji awọn ọmọbinrin Chibok gbe, wọn yoo ti se awari wọn.
Oby ni ti oun ba di aarẹ orilẹ-ede yii, oun yoo sọ di ilu ti wọn yoo ti ri awọn eeyan to n se daada, yatọ si bo se wa bayii.