Ṣeyi Law: Ọ̀rọ̀ ìlú yìí tó kéèyàn de aago méjì

Ṣeyi Law: Ọ̀rọ̀ ìlú yìí tó kéèyàn de aago méjì

Ṣeyi Lawrence ní ní tòótọ̀, ara àmì ìdánimọ̀ òun ni aago méjì tí òun máa ń wọ̀. Orúkọ àbísọ rẹ̀ ni Oluwaṣeyi Aletile. Gẹ́gẹ́ bíi apanilẹ́rìín, ó ti ń gòkè nínú iṣẹ́ ìdánilárayá.

Níbi ètò àgbéléwò AY Open Comedy Mic lọ́dún 2016 ni àṣeyọrí rẹ̀ ti bẹ̀rẹ̀ látìgbà náà ni wọ́n sì ti mọ̀ ọ́ ní mọ̀lúmọ̀ọ́ká apanilẹ́rìín lórílẹ̀èdè Nàìjíríà.

Ṣèyi Law ni olùdásílẹ̀ ètò apanilẹ́rìín "I must laugh".

Láti ara orúkọ rẹ̀ Oluwaṣeyi Lawrence ni mọ̀lúmọ̀ọ́ká apanilẹ́rìín kan nígbà náà lọ́hùún, Jẹdi gbà á nímọ̀ràn kó lo orúkọ tó ṣeé tajà. Ló bá mú 'Ṣeyi' látara Oluwaṣeyi àti 'Law' látara Lawrence.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí: