#67yearoldmother:ọ̀pọ̀ gbà pé àdúrà ló gbà lóri tọkọtaya Otubusin

#67yearoldmother:ọ̀pọ̀ gbà pé àdúrà ló gbà lóri tọkọtaya Otubusin

Dókítà Taofeek Ogunfunmilayo ṣàlàyé ìgbésẹ tí wọ́n gbé nípa ọna sáyẹnsì pẹlú kókó kàn pé: kò sí ìgbà tí ènìyàn kò lè di ọlọmọ laye pẹlú iranlọwọ Ọlọrun.

Àwọn ẹbi, ara, ati ọrẹ n ba awọn tọkọtaya ọlọmọ tuntun yii ku oriire. Wọn ṣalaye fun BBC Yorùbá pé onigbagbọ nitootoọ ni wọn.

Ọpọlọpọ ni wọn jẹ awokoṣe rere fun àwọn ni awujọ.