Africa: Èso tó gbajúmọ̀ jù láyé ńlọ sí oko ìparun
Africa: Èso tó gbajúmọ̀ jù láyé ńlọ sí oko ìparun
Eso ọgẹdẹ to jẹ pe ohun lo gbajumọ ju laaye ti n lọ si oko iparun nipasẹ aarun Panama.
Aarun Panama jẹ aarun ti o ma n kọlu iyẹpẹ, to si ma n ba awọn irugbin oko jẹ.
Amọ, awọn onimọ sayẹnsi ti n wa ọna abayọ nipa gbigbin ọgẹdẹ ninu yara ayẹwo lati tako aarun naa.
Nibayii, yoo to ọdun maarun ki gbingbin ọgẹdẹ naa to kari gbogbo orilẹede agbaye.