Lọ́kọ́ láya Sri Lanka: N kò wẹ'dò rí, ẹ̀rù sì bà mi gidi gidi
Lọ́kọ́ láya Sri Lanka: N kò wẹ'dò rí, ẹ̀rù sì bà mi gidi gidi
Hasini Herandi Perera jẹ́ kó di mímọ̀ pé òun kò ni òye kankan nípa wíwẹ odò sùgbọ́n òmùwẹ̀ tí ọkọ òun jẹ́ lo fún òun náà ní ìgboyà láì fòyà ewu.