Yusuf: Gbogbo àwọn olùkọ́ olójú kòmú kòlọ, ni kó para mọ́
Yusuf: Gbogbo àwọn olùkọ́ olójú kòmú kòlọ, ni kó para mọ́
Obinrin ajafẹtọ ilu kan, Ireti Bakare Yusuf, lasiko to n ba BBC Yoruba sọrọ ni, oun n ja fun awọn eeyan ti wọn ba ja ni ole ara nitori pe, wọn maa n ni isoro lati lọ fi ẹjọ sun.
O ni ọpọ awọn eeyan ti wọn n lọ fi ẹjọ sun lo maa n tabuku wọn, na ika aleebu si wọn, tabi fi wọn se yẹyẹ.
#Nomoreapp
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
O wa gba gbogbo ilu nimọran pe, ka mase kọju si ẹgbẹ kan, tabi se bii ẹniti ko kan wa, ta ba gbọ pe wọn fi ipa ẹnikan lo pọ.
O tun rọ awọn olukọ ile ẹkọ giga lati dẹkun kikọ ẹnu ifẹ tipatipa sawọn akẹkọ abẹ wọn.