'Ṣíṣe àyẹ̀wò abẹ́lé fún ẹni to fẹ̀ gba bi òṣìsẹ́ ìnú ilé lè dóólà ẹ̀mí rẹ̀'

'Ṣíṣe àyẹ̀wò abẹ́lé fún ẹni to fẹ̀ gba bi òṣìsẹ́ ìnú ilé lè dóólà ẹ̀mí rẹ̀'

Onímọ̀ nípa àyẹ̀wò àbẹ́lé, Kola Olugbodi ṣalayé pé awọn igbésẹ̀ kan wà tí ọpọ awọn araá ìlú kìí gbe ṣugbọn tó lè dóólà ẹ̀mí wọn àti ti ará ilé wọn.

Kínni awọn igbésẹ̀ yìí?

Ó sálàyé rẹ̀ ní kíkún pé o yẹ ki ẹnikẹni to ba fẹ gba eeyan sile gẹgẹ bi oṣiṣẹ ṣe iwadii to yẹ ṣaaju gbigba ẹni naa sile bẹrẹ lati iran oṣiṣe naa.

Bakan naa lo gba awọn eeyan nimọran lori awọn ohun to yẹ ki wọn mọ ni pato lori oṣiṣẹ wọn ati igbesẹ to yẹ labẹ ofin Naijiria.