Adedoyin: Tí mo bá rí Buhari, màá sọ fun kó rántí pé Ọlọ́run wà

Adedoyin: Tí mo bá rí Buhari, màá sọ fun kó rántí pé Ọlọ́run wà

Oludije fún ipo gomina labẹ aburada ẹgbẹ oselu Accord ni ipinlẹ Kwara, Ayọ Adedoyin, lasiko to n ba BBC Yoruba sọrọ sọ pé, Bukọla Saraki ko la òpópónà kankan tàbí gbé ilé isẹ́ wá bí i olorí ilé asòfin àgba tó wá láti ipinlẹ Kwara.

Bakan naa lo ni, Saraki ko se atunse ile ẹkọ kankan si ilu Ilọrin to ti wa, ka ma sẹsẹ si ipinlẹ Kwara lapapọ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Nigba to n dahun ibeere pe, to ba ri aarẹ orilẹede Naijiria, Muhammadu Buhari, ki lo maa ba sọ, Ayọ Adedoyin ni oun yoo sọ fun Buhari pe, o yẹ ko maa ranti pe Ọlọrun wa o.