Onigbajamọ: Báwo lẹ se gbọ́ èdè Yorùbá sí?

Onigbajamọ: Báwo lẹ se gbọ́ èdè Yorùbá sí?

BBC Yoruba bọ si igboro lati mọ bawọn ọmọ Kaarọ oojire se gbọ ede Yoruba si, ta si ni ki wọn fi ami si ori ọrọ yii - Onigbajamọ.

Orisirisi ami ọrọ to panilẹrin, to danilaraya, to si tun kọ ni lẹkọ la gbọ, lasiko tawọn eeyan yii n fi ami sori Onigbajamọ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

To ba jẹ ojulowo ọmọ Yoruba ni ẹyin naa, to si da yin loju pe ẹ gbọ ede Yoruba daada, tẹ si lee fi yangan nibikibi, o ya, ẹ fi ami sori Onigbajamọ