Ìyàtọ̀ wà nínú ìlépa àwọn òṣèré tíátà ayé àtijọ́ àti ìsisìnyí
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Papalolo ní ìlépa owó ni ìyàtọ̀ tó wà láàárín àwọn òṣèré tíátà àtijọ́ àti ìsisìnyí

Ti a ba n sọrọ awọn adẹrinpoṣonu to gba muṣe ni ilẹ Yoruba ati ni orilẹede Naijiria, ọkan gboogi ni Ayọ Ogunṣina ti ọpọ mọ si papalolo jẹ.

Nigba ti BBC News Yoruba kaa mọ ile rẹ nilu Ibadan fun ifọrọwanilẹnuwo, ko daju pe inu rẹ dun si ibi ti nnkan de duro lori iṣẹ sinima agbelewo bayii paapaa fun awọn to n dẹrin pẹrẹkẹ araalu nibẹ.

O ni lootọ ni wọn ni bi aye ba n yi , ki a maa ba aye yii, ṣugbọn ayipada to de ba sinima ti mu ki awọn oṣere o mu owo lọkunkundun ju ṣiṣe iṣẹ naa gẹgẹ bii akọṣẹmọṣẹ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Related Topics