Saheed Oṣupa, Taye Currency da ìlù bolẹ̀ ní Ibadan
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Saheed Oṣupa, Taye Currency sọ ibùdó ìpolongo ìdìbò Atiku di ibi àríyá

Lọjọ pipẹ wa ni ariwa ikunsinu, ija agba laarin awọn agbaagba Yoruba paapaa julọ awọn lọbalọba ni ilẹ Yoruba ti di orin ojojumọ leti awọn ọmọ Yoruba atawọn ti kii ṣe ọmọ Oduduwa.

Ṣugbọn ni bayii, ọrọ ko ri bẹẹ mọ pẹlu bi igbesẹ alaaafia ṣe n farahan laaarin awọn Ọbalaye gbogbo.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Saraki ní kí Yorùbá dìbò ààrẹ fún Atiku

Èmi kò mọ obìrin tí DSS mú rí —Aisha Buhari

Ohùn ìjálá lásán ni mo fi ń pa ẹran nínú igbó - Ọdẹ Oníjàálá

Mo fẹ́ ọkọ mi torí bó se ń kọrin, kìí se torí owó - Ìyàwó Aràrá

Ninu ifọrọwerọ ti o ṣe pẹlu BBC News Yoruba lori ikanni facebook live rẹ ni ọjọbọ, Ọọni Ilẹ Ifẹ, Adeyẹye Ogunwusi Ọjaja keji ṣalaye pe igba ọtun lo wọ aarin awọn aṣiwaju ilẹ ṣiwaju ilẹ Yoruba bayii.

Ọọni Ogunwusi ni aifagba fun ẹnikan ni ko jẹ kaye o roju atipe nibayii o ti han gbangba sawọn ọbalaye pe iṣọkan ati ifẹ laaarin wọn nikan ni awọn iran Yoruba ni orilẹede Naijiria ati okeokun to lee ṣe ara wọn ni oṣuṣu ọwọ ki wọn si tẹwọ gba ipo wọn lawujọ agbye.

Ìyàtọ̀ wà nínú ìlépa àwọn òṣèré tíátà ayé àtijọ́ àti ìsisìnyí-Papalolo

Bakan naa ni O yanana rẹ pe ko si ẹsin kan ti Ọlọrun yan ni pọṣin si ekeji nitori Ọlọrun kan naa lo ti ipasẹ Oduduwa da gbogbo ẹsin saye. O ni gbongbo to n fa wahala ati kọnunkọhọ laaarin agbaye ko ju ija ẹsin laaarin awọn ọmọ eeyan.