Olùdíje PDP fún ipò gómìnà l'Ọ̀yọ́ sọ̀rọ̀ lórí ìjà 'tó wà láàrin òun àti Ladoja'

Olùdíje PDP fún ipò gómìnà l'Ọ̀yọ́ sọ̀rọ̀ lórí ìjà 'tó wà láàrin òun àti Ladoja'

L'agbami oṣelu ipinlẹ Ọyọ, ni ṣe ni iroyin gba igboro nipa oludije fun ipo gomina labẹ asia ẹgbẹ PDP, Seyi Makinde ati gomina ana Rasheed Ladọja.

Ọrọ naa ru ọpọ loju, eyi to mu ki ikọ BBC Yoruba beere lọwọ rẹ wi pe ṣe lootọ ni pe aawọ wa laarin awọn mejeji.

Esi ti Makinde fọ lori rẹ niyii ninu fidio yii.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Bẹẹ ọpọ nipinlẹ Ọyọ gba pe Ladọja ni baba isalẹ to mu Seyi Makinde wọ agbo oṣelu.