"Bí mo bá dé ipò gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara..."
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

2019 election: Àwọn olùdíje fún ipò gómìnà nípínlẹ̀ Kwara sọ̀rọ̀ lórí ohun tí wọ́n fẹ́ ṣe

Awọn asoju ẹgbẹ oselu ọhun ni Ọmọọba Ayọrinde Adedoyin ti ẹgbẹ oṣelu Accord, Komuredi Issa Arẹmu, ti ẹgbẹ oṣelu Labour,

ati Ọmọwe Abdulmunin Yinka Ajia, ti ẹgbé oṣelu ANRP.

Asofin Abdulrasak Atunwa, ti ẹgbẹ oṣelu PDP ko fojuhan nibi ipade naa.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: