2019 Elections: Aago mẹ́sàn-án àárọ̀ ni ìjíròrò Eko yóò bẹ̀rẹ̀

2019 Elections: Aago mẹ́sàn-án àárọ̀ ni ìjíròrò Eko yóò bẹ̀rẹ̀

BBC Yoruba ti n gbe ipade ita gbangba rẹ bọ wa silu Eko.

Ọjọbọ, ọjọ kẹtadinlogun, osu Kinni ọdun 2019 ni ipade itagbangba BBC Yoruba yoo waye.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Gbọngan Academy Hall, WAEC international Centre, ni opopona Lateef Jakande ladugbo Ikẹja ni aago mẹsan owurọ ni ijiroro naa yoo bẹrẹ.

Ẹgbẹ oselu mẹrin ni yoo maa kopa ninu ijiroro naa.

Ẹ ku oju lọna