Day 24: Ǹjẹ́ O lè dìbò fún ẹni tí àlùfáà tàbí ìmámù rẹ́ bá yàn?#BBCNigeria2019
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Nigeria Elections 2019: Èrò àwọn ọmọ Nàíjíríà se ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ lóri ètó àlùfáà tàbí ìmámù lásìkò ìbò

Ọpọlọpọ awọn ọmọ Naijiria sọ wi pe, adari ile ijọsin tabi imaamu wọn ko le e sọ fun wọn, ẹni ti wọn yoo dibo fun nitori pe ẹtọ awọn ni lati dibo yan ẹni to wu awọn.

Amọ, awọn miran sọ wi pe, alufaa awọn mọ ẹni to daraju laarin awọn oludije, nitorina awọn le e tẹle imọran rẹ lasiko idibo.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: