BBC Yoruba ń pè yín sí ìpàdé ìtagbangba
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

ìpàdé ìtagbangba ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú àwọn olùdíje sípò gomina ní ìpínlẹ̀ Eko.

Ipàdé ìtagbangba ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú àwọn olùdíje sípò gomina ní ìpínlẹ̀ Eko pẹlu BBC Yoruba yoo waye ni Satide, ọjọ kẹrindinlọgbọn, osu kinni, ọdun 2019.

Ipade yii yoo tun kún fún ohun to n jẹ ara ilu lọkan ju eyi ti a ti ṣe ni Ọṣun, Kwara, Nasarawa, Gombe, Imo, àti Akwa Ibom lọ.

Bakan naa ni ipade itagbangba ti ipinlẹ Ọyọ. Abia, Kano, Delta ati Ogun ṣi n bọ lọna.