Fake News: BBC kọ́ lọ́ ṣe ètò ìrànwọ́ ìwé kíkà

Àwọn èèyàn ti ń fi àlàyé arawọn sílẹ̀ lórí òpó náà, ṣùgbọ́n BBC kò mọ̀ nípa ètò ìrànwọ́ ìkàwé kankan tó jọ mọ́ bẹ́ẹ̀ Image copyright Facebook
Àkọlé àwòrán Àwọn èèyàn ti ń fi àlàyé arawọn sílẹ̀ lórí òpó náà, ṣùgbọ́n BBC kò mọ̀ nípa ètò ìrànwọ́ ìkàwé kankan tó jọ mọ́ bẹ́ẹ̀

Ìròyìn òfegè ni ìròyìn tó ń lọ pé iléeṣẹ́ BBC ń ṣe ètò ìrànwọ́ ìwé kíkà lóríi www.giveaway-bbc.com.

Àwọn èèyàn ti ń lọ sí orí òpó ayélujára ọ̀hún àti òpó Facebook rẹ̀, https://www.facebook.com/GiveawayBBC/ tipẹ́.

Ṣùgbọ́n ilé iṣẹ́ BBC kò ní nǹkankan ṣe pẹ̀lú òpó náà.

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionìpàdé ìtagbangba ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú àwọn olùdíje sípò gomina ní ìpínlẹ̀ Eko.

Eléyìí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìròyìn òfegè tí àwọn èèyàn ń gbé ka lóde òní.

A rọ àwọn èèyàn kí wọ́n mọ̀ dájú pe ilé iṣẹ́ BBC kò ní nǹkankan ṣe pẹ̀lú òpó náà.

Nigba kigba ti BBC ba fẹ ṣe eto ni a maa n gbee soju opo wa ni bbcnewsyoruba lori facebook ati instagram pelu lori www.bbc.com/yoruba lori ikanni website wa.

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionMurphy Elégungun Rọba: Mo fẹ́ di ẹnití egungun rẹ rọ jùlọ ní àgbáyé
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media caption'Obìnrin ló ni ilé àti àdúgbò fún ìdí èyí wọ́n lè ṣe ìlú dáadáa'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionObasanjo: Atiku kìí se Áńgẹ́lì, àmọ́ yóò se dáadáa ní ìlọ́po méjì ju Buhari lọ

Related Topics