Festus keyamo: Ọ̀rọ̀ Obasanjọ sí Buhari ti di ìrégbè
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Festus keyamo: Ó pẹ́ tí Obasanjo ti ń fi ìkoríra hàn sí ààrẹ

Amofin agba Naijiria, Festus Keyamo ni gbogbo eniyan lo ri igbesẹ bi Obasanjo ṣe n bu ẹnu atẹ lu Buhari gẹgẹ bi ẹni to n gbe lẹyin ẹgbẹ oṣelu kan to si ti pẹ to ti korira Buhari.