Ẹ wo ọ̀nà àbáyọ tí àwọn olùdíje gómìnà pèsè sí ìṣòro Eko
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

BBC Debates: Àwọn olùdíje l'Eko sọ èròngbà wọn f'árá ìlú

Àlàyé àti èrò nípa ìjíròrò láàrin àwọn tó ń du ipò gómìnà ìpínlẹ̀ Eko láti ìpàdé ìtagbangba BBC Yoruba lé kenkà.

Gẹgẹ bi oludije kọọkan ṣe ṣalaye ohun ti wọn yoo ṣe.

Ibeere to pọ ju ti awọn eniyan ran ẹnu mọ ni ọna abayo ti wọn ni si sunkẹrẹ fakẹrẹ ọkọ to di di baraku ni ipinlẹ Eko to bẹẹ to jẹ wi pe gbogbo eniyan to wa nibi ipade ifọrọwerọ naa gba pe bi ara Eko ba fẹ de ibi kan ni agogo mejila ọsan, o ti gbudọ ji kuro nile lati agogo mẹta oru. Eyi si n kọ ọpọlọpọ lomiinu.