'Àwọn oun tí a kò gbọ́ ẹ́nu àwọn olùdíje ní #BBCGovDebate Eko'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

BBCGovDebate: Àwọn oùkópa fi èrò han lẹ́yìn ìjíròrò Eko

Awọn olukopa nibi ipade itangbangba fi ero wọn han nipa awọn ileri ti wọn gbọ lẹnu awọn oludije fun ipo gomina Eko.

Awọn kan ṣe ni awọn reti lati gbọ ọrọ to jinlẹ nipa eto ẹkọ, eto ọgbin, ati alaye kikun lori ilé kikọ fawọn ara ilu bii ti ayé Jakande.

Ọpọlọpọ lo gboriyin fun BBC agbaye fun inawo ati inara ti wọn ṣe lati gbe eto yii kalẹ.

Ipade itagbangba naa waye ni ọjọ Abamẹta, ọjọ kẹrindinlọgbọn, oṣu kinni, ọdun 2019 nilu Eko.

Àwọn ìròyìn mìíràn tí ẹ lè nífẹ̀ẹ́ sí:

Eyi ti awọn oludije naa ko sọrọ nipa, ni awọn kan ni awọn ko ni ireti pupọ ninu awọn ileri ti awọn oludije naa sọ.