A ò ṣe àyọnusọ lóri ọ̀rọ̀ abẹ́lé Nàìjíríà-UK
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Onnoghen: Irọ́ ni pé a ń dásí

Ìjọba ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì ti tako ẹsùn tí ijọba Nàìjíríà fi kàn-án pé, òun àti awọn agbódegbà kan ń tojúbọ ọ̀rọ̀ abẹ́lé Náíjíríà.

Pàápà jùlọ lórí ọ̀rọ̀ Walter Onnoghen tó jẹ́ adájọ́ àgbà tí wọn yọ ní fẹ̀rẹ̀ kí ìdìbò gbogboogbo.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: