Hubert Ogunde ló m'órí mi yá láti di òṣèré
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Wale Rapper: Ìya mi gan ti lè yára sọ̀rọ̀ bí ẹni ń kọrin

Adewale Adepoju jẹ ọmọ Yoruba lati ilu Ọyọ to si jẹ wi pe lati ile iwe giga fasiti to lọ lo ti yan lati maa ṣe ohun to jọ mọ itage. Sisare sọrọ ninu orin ti wa di aṣa ninu idile wọn.

Related Topics