Ilé ẹjọ́ dájọ́ ikú fún àwọn tó pa Tìmílẹ́hìn, akẹ́kọ̀ọ́ fásitì UNIOSUN l'Oṣogbo

Awọn ọdaran naa Image copyright Ope'biosu
Àkọlé àwòrán Oṣù kẹfà ọdún 2017 ni wọ́n ṣekúpa akẹ́kọ̀ọ́ fásitì UNIOSUN náà nílùú Òṣogbo

Ile ẹjọ giga ipinlẹ Ọṣun kan to fikalẹ silu Oṣogbo ti dajọ iku fun awọn ọdaran mẹta kan ninu marun ti wọn fi ẹsun kan pe wọn lọwọ ninu pipa akẹkọ fasiti ipinlẹ Ọṣun kan ti orukọ rẹ n jẹ Ṣonibarẹ Timilẹhin.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Ni ọjọ kẹrindinlọgbọn, oṣu kẹfa, ọdun 2017 ni awọn agbenipaṣowo kan pa akẹkọ onipele kẹrin fasiti UNIOSUN ni agbegbe Oke Baalẹ ni ilu Oṣogbo.

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionAdemọla Ogunbanjo: A nílò bàbá ìsàlẹ̀ nínú òsèlú

Odo ni wọn fi pa ọdọkunrin naa nigba naa ki wọn to ko oku rẹ si inu odo ninu ibi ti wọn ti n gun un.

Ẹkunrẹrẹ iroyin yii n bọ laipẹ...

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media caption'A ni òfin púpọ̀ ní Naijiria ṣùgbọ́n a kò bọ́wọ́ fún un ni'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionFalana: Awọn to n dije dupo ìdìbò 2019 fẹ́ fa ogun si Naijiria