#NigeriaDecides: Buhari Sudan ló n díje dupò aàrẹ -Nnamdi Kanu (IPOB)
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Nnamdi Kanu sọrọ lórí àwọn oludije PDP àti APC

Kanu ṣalaye lori ọna ti oun gba bọ́ mọ́ àwọn ologun lọwọ nitori pe alejo kàn loju lagbari ni, wọn ko lè fi riran to ọmọ onilẹ.

Nnamdi Kanu to jẹ olori awọn ajajangbara fun ominira iran Igbo ni Naijiria ti a mọ si IPOB ṣalaye ijọra ati iyatọ to wa lara Buhari ati Jubril ti ilẹ Sudan.

Bakan naa lo mẹnuba ọrọ Abubakar Atiku to n dije dupo lẹgbẹ oṣelu PDP.

Kanu sọrọ lori ọna ti oun fi dawati lọwọ awọn ologun ti wọn ni ko wa gbe e tẹlẹ nigba ti o n ba akọroyin BBC sọrọ.