#NigeriaDecides: Àwọn ohun to ní láti mọ̀ ní pa idibò 2019

Idibo Nigeria 2019

Pẹ̀lú bí àwọn oloṣelu ṣe ń naá owo ni akoko idibo ni Naijiria, ọpọlọpọ ni yoo ro pe, ko si iye ti wọn ko le naa lori oṣelu.

Ṣugbọn ko ri bẹẹ. Ofin orilẹede Naijiria ṣe alakalẹ gbedeke iye owo ti wọn le naa lori didije.

Àwọn ìròyìn mìíràn tí ẹ lè nífẹ̀ẹ́ sí:

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media caption#BBCNigeriaElections: Ọmọ Ogun iṣẹ́ yá -Adarí àjọ elétò ìdìbò Ogun