Àwọn òṣìṣẹ́ BBC News Yorùbá sọ̀rọ̀ ìdùnnú lórí ayẹyẹ ọdún kan iléeṣẹ́ náà

Ni aarin ọdun kan ti BBC News Yoruba ti bs sori afẹfẹ, oniruuru iroyin manigbagbe ni o ti gbe sita eleyi ti o ti rinlẹ kọja orilẹede Naijiria lọ.

Awn oṣiṣẹ to wa nidi ikoko ọbẹ to n dana agbọn-ọn-gbẹ iroyin wọnyii ṣalaye iriri wọn.

Orin ọpẹ lo gba ẹnu wn kan.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: