Nigeria 2019 Elections: Àwòrán bí Ilọrin ṣe gbàlejò Yẹmi Ọṣinbajo

Wọnyi ni akojọpọ aworan abẹwo Igbakeji Aarẹ, Yemi Osinbajo si Ilu Ilorin.

Aworan igbakeji Aarẹ ni ilu Ilorin
Àkọlé àwòrán,

Igbakeji Aarẹ Yemi Osinbajo dupẹ lọwọ Emir Ibrahim Zulu Gambari fun bi wọn ti ṣe n gba gbogbo ẹgbẹ lalejo lalai ṣegbe lẹyin ẹgbẹ kankan

Àkọlé àwòrán,

Awọn alatilẹyin ẹgbẹ APC meji yi n fi ifẹ han si igbakeji Aarẹladugbo Adeta nilu Ilorin

Àkọlé àwòrán,

Niwaju Mosalasi nla ilu Ilorin,awọn alatilẹyin ẹgbẹ APC n juwọ si Igbakeji Aarẹ

Àkọlé àwòrán,

Emir ilu Ilorin, Maimartaba Ibrahim Zulu Gambari gbalejo Igbakeji Aarẹ Yemi Osinbajo

Àkọlé àwòrán,

Igbakeji Aarẹ kọwọrin pẹlu awọn ọmọ ẹgbẹ APC lasiko abẹwo naa

Àkọlé àwòrán,

Abdulrahaman Abdulrazaq to n du ipo Gomina labẹ asia APC lo joko si apa ọtun Emir Ilorin

Àkọlé àwòrán,

Awọn ọmọ ẹgbẹ APC ladugbo Gaa Arẹmu nilu Ilorin tuyaya lati pade Igbakeji Aarẹ