Election Update 2019: Ologun ni Wike gbe owo kalẹ pe kawọn fi da ibo ru

Nibi ipade awọn akọroyin ti awọn ologun se ni wọn ti fẹsun kan gomina Nyesom Wike pe o fun awọn lowo lati da ibo Satide ru.