'Mi ò ní Bàbá ìsàlẹ̀ ṣùgbọ́n mo ní Bàbá òkè' - Adedoyin
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Kwara Politics: Ayo Adedoyin ti ẹgbẹ Accord Kwara sọ̀rọ̀ lórí níní bàbá ìsàlẹ̀

Ayo Adedoyin to jẹ oludije sipo gomina ni ipinlẹ Kwara labẹ asia ẹgbẹ oṣelu ACcord bu ẹnu atẹ lu ọrọ baba isalẹ ninu oṣelu.

O ni nigba toun fi bẹrẹ oṣelu, wọn ni oloṣelu ori ayelujara ni awọn ṣugbọn wọn ko mọ pe ẹrọ ayelujara yẹn gan lo wulo tori ohun lo lu jara kari aye.

"Ohun gan wa lara nkan to gbe wa jade".