"Ọmọ méjì kú fún mi láàárín ọjọ́ mẹ́jọ, ṣùgbọ́n..."
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Sẹ́gílọlá: Arúgbó awẹ́lẹ́wà tó ń ṣiṣẹ́ omidan

Awọn agba bọ wọn ni arugbo ṣoge ri akisa lo igba ri. Eyi gan lo difa fun Sẹgilọla, iya agba to n ṣiṣẹ afaworan ṣoge, (modelling) ti ọpọ mọ mọ awọn omidan.

Gẹgẹbi ohun to sọ fun BBC News Yoruba, ko si ara ti omidan iwoyi n da ni oge ati ẹṣọ ti awọn arugbo ko tii fi lo gba nigba tiwọn.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: