Oshisko twins, àwọn ìbejì tó ń dẹ́rìn ín p'òṣónú
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Oshisko twins: Ojú wa rí, ṣùgbọ́n ìgbọ́raẹniyé ló ń ràn wá lọ́wọ́

Ibeji tootọ kọ ni Adigun Ọmọbọlanle Valentina pẹlu Oyedele Adebisi Yewande ṣugbọn wọn ti sọ ara wọn di ejirẹ ẹdunjọbi oyila lẹnu iṣẹ adẹrinpoṣonu lori ikanni agbaye Twitter, Instagram ati Facebook ni wọn.

Amọṣa, ki lo sun wọn yan orukọ, 'Oshisko twins' ati pe ki ni awọn ipenija ti wọn n dojukọ gẹgẹ bii ọrẹ meji to sọ ara wọn di ibeji ti wọn si tun yan iṣẹ amuludun laayo?

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: