Kí ni àmì ohùn 'Aguntaṣọọlo'?
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Kí ni àmì ohùn 'Aguntaṣọọlo'?

Gbajugbaja ni ọrọ yii, "Aguntaṣọọlo" paapaa laarin awọn alagbe, olorin atawọn iyaagba ti wọn fẹ ki awọn ọmọ wọn.

Awọn olorin a ni, 'aguntaṣọọlo, ọkunrin ogun' ati bẹẹbẹẹ lọ; ṣugbọn ki ni ami ohun ti ede Yoruba fi si ori ọrọ yii?

Ẹ gbiyanju tiyin, ti awọn ololufẹ BBC News Yoruba kan ree.

Related Topics