Lagos collapsed building: Àwọn èèyàn ìpínlẹ̀ Eko ní ìjọba, aráàlú lọ́wọ́ nínú bí ilé ṣe ń wó

Lagos collapsed building: Àwọn èèyàn ìpínlẹ̀ Eko ní ìjọba, aráàlú lọ́wọ́ nínú bí ilé ṣe ń wó

Ile ko ṣẹsẹ maa wo ni ipinlẹ Eko ati kaakiri Naijiria, ṣugbọn gbọnmọgbọnmọ rẹ ni ẹnu ọjọ mẹta yii ti fa ọpọ si ajọ to nironu.

Ni bayii, ati ijọba ataraalu ni wọn ti gba pe ki awọn iṣẹlẹ ile to n da wo lorilẹede Naijiria, paapaa julọ nipinlẹ Eko to lee di afisẹyin ti eegun n fiṣọ awọn igbesẹ gbogbo to yẹ gbọdọ waye.

Ki ni awọn igbesẹ yii? Labare ree...

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: