Wo àwọn ọmọge Sanwo-Olu tó ń dun Tinubu nínú
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Tinubu: Nítorí Tinubu, àwọn ọmọge Sanwo-Olu da ìlù bolẹ̀

Obinrin ni iyọ aye. Awọn eeyan kan tilẹ tun pa aṣamọ rẹ pe awọn gan tun ni iyọ oṣelu.

Lara awọn obinrin to jẹ iys oṣelu ni ipinlẹ Eko ni Sanwo-olu babes wa. Awọn ni amuludun fun eto gbogbo ti ẹgbẹ oṣelu APC nipinlẹ Eko ba gbe kalẹ lọwọlọwọ.

Ẹ pade wọn ninu fidio yii.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: