Wo obìnrin tó ń múra bíi ọkùnrin láti leè ṣe 'iṣẹ́ ọkùnrin'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Neha Sharma: obìnrin tó ń múra bíi ọkùnrin láti leè ṣiṣẹ́ gẹrígẹrí

Idẹyẹsi jẹ ohun ti awọn obinrin awujọ lorilẹede India n ba finra gẹgẹ bii awọn obinrin lọpọlọpọ orilẹede agbaye.

Nitori ati lee ṣe iṣẹ ti ọkan rẹ fẹ, Nehar Sharma ni lati daa bi ọgbọn nitori ati lee ṣe iṣẹ ti o yan laayo.

Labare ree lori awọn igbesẹ ti o gbe lati mu ala rẹ ṣẹ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: