Ayekofẹnifọrọ: Ó yá, ẹ fi àmì sórí ọ̀rọ̀ náà.

Ayekofẹnifọrọ: Ó yá, ẹ fi àmì sórí ọ̀rọ̀ náà.

Ẹ̀rín kèé-kèé ni báwọn èèyàn ṣe fi àmì sórí ọ̀rọ̀ 'Ayekofẹnifọrọ'

Ami ori ọrọ ṣe pataki ninu ede Yoruba, o si yẹ ka maa kọ ara wa, tabi ran ara wa leti.

Idi ree ti BBC Yoruba ṣe bọ sigboro, ta si ni ki awọn ọmọ Oodua fi ami si ori ọrọ: Ayekofẹnifọrọ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Iroyin ko to afojuba ninu fidio yii, nibi ti ẹrin yoo ti pa yin nipa oniruuru ami tawọn araalu fun ọrọ naa.

Ṣugbọn ẹ ma lọ, lai fi ami si ori ọrọ naa, Ayekofẹnifọrọ.

Aṣa ati iṣe ati ede Yoruba ṣe pataki pupọ fọmọ Oodua, ẹ jẹ ki gbogbo wa kọ awọn ọmọ wa nipa wọn fun idagbasoke, irẹpọ ati ifẹ ni awujọ wa.