Kọ́ ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ ìbálọ̀pọ̀- Ọ̀jọ̀gbọ́n Fagbohungbe
Kọ́ ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ ìbálọ̀pọ̀- Ọ̀jọ̀gbọ́n Fagbohungbe
Ọjọgbọ Fagbohungbe Bankole Oni sọ pe awọn obi aye ode oni ko ṣiṣẹ wọn bii iṣẹ mọ. O woye pe eleyi lo n ṣe okunfa ki awọn ara ita maa fipa ba awọn ọmọ kekeke tage tabi ni ibalopọ.
O sọrọ yii ninu ifọrọwerọ pẹlu BBC Yoruba nigba ti o n sọ iwoye rẹ lori akẹkọọ ọmọ ọdun mẹrin ti awakọ kan ba fipa ba tage.
O gba awọn obi niyanju lati maa kọ awọn ọmọ wọn lẹkọ ibalopọ lati igba ti wọn be ti wa ni kekeke.