Nkwocha Ernest: Ìdọ́tí ni wọ́n ń pè é ṣùgbọ́n èmi pè é ni ohun èlò

Nkwocha Ernest: Ìdọ́tí ni wọ́n ń pè é ṣùgbọ́n èmi pè é ni ohun èlò

Nkwocha Ernest jẹ agbẹ́ ère lọna ara ọtọ. Awọn aloku taya ọkọ lo fi n ṣe iṣẹ ọna tirẹ. A maa ṣa awọn taya ti wọn ko lo mọ kiri ilu Eko.

Eredi to fi n ṣe iru iṣẹ ọna yii ni lati gba ilu Eko mọ kuro ninu idọti isẹ r yii si ti n gbajugbaja bayii lorilẹede Naijiria.

Sugbọn bayii, o fẹ lati gbe iṣẹ ọna fifi táyà ọkọ̀ gbẹ ere yii de ibi giga kaakiri agbaye.

Nigba ti BBC ba a lalejo ni ẹnu iṣẹ rẹ, Ernest ṣalaye pe nigba mii, bi taya ọkọ ṣe ri lo maa n fun oun ni imisi ohun ti yoo pa a lara da si.