Wọnyi ni Àkójọpọ̀ àwọn àwòrán mánigbàgbé ọdún Àjínde l'Afrika.
Ẹ fójú lóúnjẹ lórí àkójọpọ̀ àwọn àwòrán mánigbàgbé ọdún Àjínde l'Afrika

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Aworan ajọdun ajinde l'Afrika
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ajọdun ajinde jẹ ọdun pataki fun awọn ẹlẹsin Kristẹni l'Afrika
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Lati Naijiria titi to fi de South Sudan lawọn Kristeni n ṣe ajọdun ọdun yi
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Awọn olujọsin a ma ṣe ere to ṣe afihan iṣẹlẹ to waye lọjọ ajinde
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Lati ọjọ ẹti rere titi di ọjọ aiku ni ajọdun yi fi n waye
Oríṣun àwòrán, SEYLLOU
Awọn ọmọ ijọ a ma kopa ninu ajọdun naa lati fi pataki ọdun ajinde han
Oríṣun àwòrán, BRIAN OTIENO
Lorileede Kenya naa,awọn naa kopa ninu ajọdun ajinde