House on water: Ǹjẹ́ ìwọ lè gbé ilé tó wà lórí omi?

Ajọ iṣọkan agbaye ni eeyan bi ẹgbẹrun mẹwaa ni yoo maa gbe ile to wa lori omi laipẹ laijina.

Ilu ti yoo wa lori omi yii ni yoo maa ṣe ipese ounjẹ ati ina ati omi pẹlu dida idọti rẹ nu lọna igbalode fun ara rẹ.

Ajọ iṣọkan agbaye ni ilu yii le jẹ ọna abayọ si ẹkun omi to n de ba okun.

Awọn eeyan to n gbe lagbegbe omi ni yoo kọkọ jẹ anfani yii.