Yemi Blaq: Ìyàwó mi lọ́wọ́ sí kí n fẹnuko obìnrin míì lórí ìtàgé

Yemi Blaq: Ìyàwó mi lọ́wọ́ sí kí n fẹnuko obìnrin míì lórí ìtàgé

Adúmáadán ọkunrin òṣèré Tíátà tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn ni Yemi Olatunji Blaq. O tun gbaju gbaja gẹgẹ bi ọdọ oṣere to ti di mọlumọọka.

Ipinlẹ Ondo ni a gbe bi i to si gbe fun igba diẹ lati kekere rẹ. Lati igba yii ni ayanmọ rẹ ti rọ mọ iṣẹ ere tiata ti ko si rẹwẹsi lori rẹ.

Iyawo rẹ ni Remi Blaq ti oun naa jẹ akọtan ere ati òṣere to maa n fara han fun ipa pataki ninu ere.

Lati ọdun 2005 ni Yemi Blaq ti kara bọ awujọ awọn elere Yoruba, Yollywood àti ti gbogbo Naijiria lapapọ, Nollywood to si ti ṣe deedee lati igba naa ti awọn ololufẹ rẹ gẹgẹ bi oṣere si n gbayii awọn ere rẹ