Àwọn òbí mi rò pé ẹ̀jẹ́ ti ta sí ọpọlọ mi nígbà tí mo bẹ̀rẹ̀ sí ba ẹranko igbó ṣọ̀rẹ́

Àwọn òbí mi rò pé ẹ̀jẹ́ ti ta sí ọpọlọ mi nígbà tí mo bẹ̀rẹ̀ sí ba ẹranko igbó ṣọ̀rẹ́

Itọ́jú ati ídáábò bo ẹranko igbo ni ọpọlọpọ awọn eniyan ti mu ni ọkunkun dun kakakiri agbaye, nitori wipe ọpọlọpọ awọn ẹranko naa ni wọn ti fẹ pa tan fun oniruuru idi.

Ṣugbọn ọmọbinrin yii, Maureen, ọmọ orilẹede Kenya, pinnu lati kekere lati maa tọju ẹranko igbo.

Àwọn ìròyìn mìíràn tí ẹ lè nífẹ̀ẹ́ sí: