Oṣu mẹ́rin la fi jà kí wọ́n tó ó tú Zainab sílẹ̀ l'ẹ́wọ̀n
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Zainab Aliyu: A kò mọ́ pé wọ́n kẹ́ òògùn olóró sí àbúrò mi l'ọ́rùn- Hajara

Lẹyin ti iroyin jade pe wọn ti fi Zainab Aliyu si ẹwọn ni Saudi Arabia, ni awọn kan bẹ̀rẹ̀ iwọde ati ipolongo pe ki wọn o tu u silẹ.

Ipolongo naa de ori ẹrọ ayelujara.

Bí Zainab ṣe dèrò ẹ̀wọ̀n Saudi lórí ẹ̀sùn ògùn olóró tí kò mọ̀

Ìjọ̀ba Saudi ti tú Zainab tí wọ́n fẹ̀sùn òògùn olóró kàn sílẹ̀

‘Bí ẹ se gba Zainab sílẹ̀, ẹ gba Leah Sharibu lọ́wọ́ Boko Haram’

Ọgbọnjọ oṣu Kẹrin ni o gba ominira kuro ni ẹwọn lẹyin ti ijọba Naijiria da si ọ̀rọ̀ naa.