Yomi Fabiyi, Abbey Lanre ń rọbi lórí Àgbésọrísùn
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Nollywood: Bẹbẹ ń lọ ní ibùdó yíya sinimá Àgbésọrísùn

Sinima ṣiṣe lorilẹede NAijiria ti di itẹwọgba lagbaye, ṣugbọn bawo ni awọn sinima yii ṣe n parapọ di ohun ti araye n tẹwọgba?

idahun si ibeeere yii lo sun ikọ BBC News Yoruba lọ si ibudo iya sinima kan ti akọle rẹ n jẹ Àgbésọrísùn.

Yọmi Fabiyi lo kọ ere naa, Abbey Lanre lo si dari rẹ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: