Ọmọ ọdún méjìlá ṣe katakata tó ń ṣiṣẹ́
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Coding Kids: Ẹ wo àrà t'àwọn ọmọ kékeré ń fi ẹ̀kọ́ kọ̀mpútà dá

Ọmọ ti yoo ba jẹ Aṣamu, ati kekere lo ti n ṣẹnu ṣamuṣamu. Gẹgẹ bẹẹ lọrọ Oluwatobiloba Nsikakabasi Owolola to jẹ ọmọ ọdun mejila ati Fathia Abdullahi t'oun naa jẹ ọmọ ọdun mejila ri.

Awọn mejeeji ni wọn fi imọ ''coding'' ninu ẹkọ kọmputa dara nla.

Oluwatobiloba ni tirẹ ṣe katakata to maa n ko nnkan lati ibikan si imiiran, nigba ti Fathia ṣe ẹrọ to n maa kaṣọ.

Ko da awọn obi awọn mejeeji jẹri wi pe iwuwasi awọn naa yatọ nile lati igba ti wọn ti bẹrẹ ẹkọ ''coding'' lori lori ẹrọ kọmputa.