Ramadan: ọmọ ọdún mẹ́wàá sọ ìrírí rẹ̀ pẹlú Àwẹ̀

Ramadan: ọmọ ọdún mẹ́wàá sọ ìrírí rẹ̀ pẹlú Àwẹ̀

Awẹ, ọkọ ẹni tii gba ni awọn alaawẹ musulumi a ma wi.

Ninu awọn origun ijọsin musulumi,awẹ gbigba ninu oṣu Ramadan jẹ ọkan gbogi.

Fun ẹni ti ko ba mọ lara,awẹ a ma muinira wa ṣugbọn lọdọ ọmọdebinrin Nadia lati ilu Mombassa lorileede Kenya,o ni yatọ si awẹ akọkọ to mu inira wa diẹ,ohun kii m ala awẹ lara.

Bawọ ni o ti ṣe ma n ṣe ti awọn akẹgbẹ r to ku ba n jẹ ounjẹ ni ile iwe?

Ẹ wo iriri rẹ ati amọran to ni fawọn miran to ba n gba awẹ.